Omo I got the message sha 🥴
Opo to gbe sama duro, ti awon omo eniyan ba mo, tiwon ba lo mo ibi to wa, won ti ni kiwon wu kuro, toba se won lagbara lori panorama won a ti ni kiwon jojumi, sugbon Olohun lo juwon lo, lo gbewa bori awon kenimamani asebi!!!